Ojo Maduekwe
Ojo Maduekwe | |
---|---|
Minister of Transportation | |
In office 2001–2003 | |
Asíwájú | Kema Chikwe |
Arọ́pò | Precious Sekibo |
Foreign Minister of Nigeria | |
In office July 26, 2007 – March 17, 2010 | |
Asíwájú | Joy Ogwu |
Arọ́pò | Henry Odein Ajumogobia |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Abia State, Nigeria | Oṣù Kàrún 6, 1945
Aláìsí | June 29, 2016 Abuja, Nigeria | (ọmọ ọdún 71)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party |
Chief Ojo Maduekwe /
Ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó kẹ́kọ̀ọ́ ní University of Nigeria, Nsukka, ó sì gboyè ẹ̀kọ́ nínú ìmọ̀ òfin ní ọdún 1972.[1]
Iṣẹ́ òṣèlú tó yàn láàyò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ṣọ́n yàn án sípò Mínísítà tó ń rí sí ọ̀rọ̀ ilẹ́ òkèèrè ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríàní ọjọ July 26, 2007 láti ọwọ́ President Umaru Yar'Adua.[2] Ó kúrò lórí oyè ní oṣù March 2010 lásìkò tí Ààrẹ Goodluck Jonathan wó ẹgbẹ́ náà kalẹ̀.[3] Òun ni National Secretary ti ẹgbẹ́ olóṣèlú Peoples Democratic Party (PDP). Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i igbákejì olùdarí fún ìpolongo ìdìbò ti ọdún 2011 lábẹ́ Goodluck/Sambo. Wọ́n yàn án fún SGF, àmọ́ wọ́n padà mu sílẹ̀ nítorí ìkùnsínú àwọn ènìyàn láti apa Ìlà-oòrun ilẹ̀ Nàìjíríà.
Tẹ̀lẹ̀tẹ́lẹ̀, wọ́n yan Maduekwe gẹ́gẹ́ bí iMínísítà tó ń rí sí àṣà àti Tourism gba ọwọ́ ààrẹ Olusegun Obasanjo ní ọdún1999.[4]
Ọ̀rọ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Maduekwe àti alága NDDC ìgbà kan rí, Onyema Ugochukwu wà nínú ẹgbẹ́ kan náà ní University of Nigeria[5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Nigerian Transport Minister Out Spoken On Bike". Vanguard. July 2001. Archived from the original on 2010-06-13. Retrieved 2010-02-08. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Nigerian president names three to Cabinet energy posts, warns against graft", Associated Press (International Herald Tribune), July 26, 2007.
- ↑ Daniel Idonor (17 March 2010). "Jonathan Sacks Ministers". Vanguard. Retrieved 2010-04-14.
- ↑ Seyi Oduyela (January 1, 2006). "State of The Nation: Countdown To 2007". Dawodu. Retrieved 2010-02-08.
- ↑ Patrick Henry (January 7, 2007). "Political Rumors and Surprises: The Dust has Cleared". NgEX!. Archived from the original on 2010-01-13. Retrieved 2010-02-08.
Preceded by Vincent Ogbulafor |
National Secretary of the PDP 2003 – 2016 |
Succeeded by Vacant |
The Cabinet of President Umaru Yar'Adua, which was formed on 26 July 2007, is shown below. The list shows Federal Ministers but excludes Ministers of State, who assist the Federal Ministers.
The cabinet was dissolved on 17 March 2010 by Acting President Goodluck Jonathan, and a new cabinet sworn in in 6 April 2010. | |||||||||||||||||||||||||||||||||
| |||||||||||||||||||||||||||||||||
| |||||||||||||||||||||||||||||||||