(Translated by https://www.hiragana.jp/)
Ẹ̀bùn Ọ́skà - Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́ Jump to content

Ẹ̀bùn Ọ́skà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Academy Awards)
Ẹ̀bùn Ọ́skà
Ère ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù Amẹ́ríkà
Bíbún fún fún iṣẹ́ takuntakun ní ilé iṣẹ́ fíìmù Améríkà
Látọwọ́ Academy of Motion Picture Arts and Sciences
Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
Bíbún láàkọ́kọ́ May 16, 1929
Ibiìtakùn oníbiṣẹ́ Oscars.org

Àwọn Ẹ̀bùn Akádẹ́mì tàbí Ẹ̀bùn Ọ́skà jẹ́ ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù tí American Academy of Motion Picture Arts and Sciences ma ń fún olùdarí eré, òṣèrè àtí olùkọ̀tàn fún iṣẹ́ takuntakun ní ilé iṣẹ́ fíìmù.[1] Ayẹyẹ ẹ̀bùn yìí jẹ́ ìkan lára àwọ́n ayẹyẹ èbùn tó lókìkí jùlọ ní gbogbo àgbáyé. Osì tún jẹ́ Ayẹyẹ ẹ̀bùn tó pẹ́ júlọ tí ó si ma ń dàgbeléwò lórí ẹ̀rọ amóùnmáwòran ní orílẹ̀ èdè tó ju igba lọ. Aẁọn ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù bi tiẹ̀ ni Grammy Awards (fún orin), Emmy Awards (fun amóùnmáwòran), àti Tony Awards (fún tíát̀à)

  1. "About the Academy Awards". Academy of Motion Picture Arts and Sciences. Archived from the original on April 7, 2007. Retrieved April 13, 2007.