(Translated by https://www.hiragana.jp/)
Achistrum - Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́ Jump to content

Achistrum

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòrán achistrum

Achistrum
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Ẹgbẹ́:
Ìtò:
Ìdílé:
Ìbátan:
Achistrum

Achistrum jẹ́ ìdílé kòkúmbà òkún tí a kò rí mọ́ ṣùgbọ́n tí a ti rí tẹ́lẹ́ ni Poland ní ìgbà Triassic, àti ní  United States  Ìgbà Eléèédú.[1] Àwọn ẹ́yà tí ó wà nínú rẹ̀ ni  Achistrum nicholsoni àti Achistrum ludwigi.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]