Angela Emuwa
Ìrísí
Angela Emuwa | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Olufunmilayo |
Ààyè lọ́wọ́ | Active |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | Olufunmilayo |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | ESUT Business School |
Iṣẹ́ | Media executive, Journalist |
Organization | Punch Media Foundation |
Predecessor | Gbadebowale Aboderin |
Parent(s) |
|
Angela Olufunmilayo Emuwa jẹ́ adarí àwọn oníròyìn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ alága Punch Media Foundation, tí àwọn ìgbìmọ̀ Punch Nigeria Limited yàn ní ọdún 2018, lẹ́yìn ikú ẹ̀gbọ́n rẹ̀ Gbadebowale Wayne Aboderin, ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 2018.[1] Kí wọ́n tó yàn án sípò gẹ́gẹ́ bí alága, ó ti dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ náà ní ọdún 1994, ó sì ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi olùdarí tí kì í ṣe aláṣẹ ilé-iṣẹ́ náà.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Our Board – PUNCH Media Foundation" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved November 13, 2021.