Charles Okocha
Ìrísí
Charles Okocha | |
---|---|
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | Igwe 2Pac |
Iṣẹ́ | Actor |
Gbajúmọ̀ fún | bad boy roles |
Charles Okocha tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Igwe 2Pac jẹ́ òṣèrékùnrin orílẹ́-èdè Nàìjíríà tó gbajúmọ̀ fún ṣiṣe ẹ̀dá-ìtàn ọmọ burúkú nínú eré.[1] Charles Okocha jé ọ̀kan lára àwọn àwòkọ́ṣe fún 'Idea Challenge, èyí tí Nigeria Billionaires Network gbé kalẹ̀.[2] Ó gbégbá orókè nínú ìdíje ti Vskit Voice ní ọdún 2019.[2][3]
Ìgbésí ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2019, ọlọ́pàá kan ṣèṣì yìnbọ fun, èyí sì mu kí ó lọ fún iṣé abẹ ní òkè òkun.[4][5]
Àríyànjiyàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Fọ́nrán kan tàn ká lórí ayélujára tó múnú bí àwọn olólùfẹ́ rẹ̀. Wọ́n fẹ̀sùn kan òṣèrékùnrin yìí pé ó ba ọkọ̀ ọ̀rẹ́ rẹ̀ jẹ́, tí ó sì ń fa ọmọ ọ̀rẹ́ náà sínú ọkọ ìmíì.[6] Charles Okocha yanjú ọ̀rọ̀ náà, ó sì ṣàlàyé pé fọ́nrán náà jẹ́ àgékúrú fíìmù kan tí ó ṣe.[6]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "My mum wants me to act as pastor, not just bad boy — Charles Okocha". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-06-05. Retrieved 2022-12-09.
- ↑ 2.0 2.1 "Charles Okocha, others to mentor youths in ‘Idea Challenge’". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-11-18. Retrieved 2022-12-09.
- ↑ Royal, David O. (2019-11-07). "Charles Okocha a.ka ‘Igwe 2pac’ wins Vskit Voice to Fame crown". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-09.
- ↑ Okogba, Emmanuel (2019-06-25). "Actor Charles Okocha expresses gratitude after successful surgery in U.S". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-09.
- ↑ Jannah, Chijioke (2017-08-18). "Popular Nollywood actor, Charles Okocha, narrates how he survived 6 gunshots in Asaba". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-09.
- ↑ 6.0 6.1 "Viral video: My daughter's image at stake - Actor Charles Okocha". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-22. Retrieved 2022-12-09.