(Translated by https://www.hiragana.jp/)
Gbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè - Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́ Jump to content

Gbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti GDP)
Ṣíṣe ìṣirò ìpawó orílẹ̀-èdè.

Gbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè (GIO) ni ona iwon gbogbo okowo orile-ede kan. Eyi ni iye owo itaja gbogbo oja ati isisefun to waye ninu bode orile-ede kan larin odun kan.