Bíbélì Mímọ́
Ìrísí
Bíbélì Mímọ́, tabi Bíbélì jẹ́ àkójọpọ̀ àwọn ìwé Ẹ̀sìn Ju àti Ẹ̀sìn Kristi.
Bibeli Heberu tabi Bibeli Awon Ju da si apa meta:
- Torah, tabi "Ilana" ti a mo si Pentatefki tabi "Iwe Marun Mósè"
- Nefimu, tabi "Awon Woli"
- Ketufimu, "Akole mimo"
Bibeli awon Ẹlẹ́sìn Kristi da si apa meji.
Apa Kinni
Apa Keji
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |